Home LÁGBO ÀRÍYÁ Mo kàn fi àkókò ṣòfò gẹ́gẹ́ bí apanilẹ́rìín. –Tẹ́jú Babyface.
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 6, 2017

Mo kàn fi àkókò ṣòfò gẹ́gẹ́ bí apanilẹ́rìín. –Tẹ́jú Babyface.

Ọgbẹni Tẹju Oyelakin ti gbogbo eniyan mọ si Tẹju Babyface ti jẹ ka mọ pe gbogbo ọdun ti oun fi jẹ apanilẹrin, ifakoko ṣofo gbaa ni.

O sọ eyi laipẹ yi nigba ti o n gba awọn eeyan nimọran nipa ailowo lọwọ. O ni eeyan ni lati mọ ohun ti Ọlọrun fẹ ko ṣe nitori igba yẹn gan gan ni eeyan ma ṣe iṣẹ irọrun ti yoo si ni owo lọwọ.

O ni oun ri daju pe olukọ ni oun fẹ jẹ, eyi ti o n ṣe lọwọ bayi. Nipa eyi ni o fi kọ iwe ‘Secrets of the Streets’ (Aṣiri ilakaka) eyi ti o n ta lọwọ lọwọ bayii. Iwe naa daleri bi a ṣe le mu ala wa ṣẹ nipa didi eniyan pataki lawujọ.

 

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…