Fayose dá ẹgbẹ́ òsèlú PDP sí méjì l’Ékìtì
Lati ojo to ti pe ni gomina ipinle Ekiti, Oloye Ayodele Fayose ti salaye pe Olorun lo maa fa gomina kale ni ipinle Ekiti, bayii o ti fa igbakeji re, ogbeni Olusola Kolapo kale lati dije du ipo gomina fun egbe oselu PDP lodun to n bo.
Awon oloye egbe bii Ogbeni Adedayo Adeyeye, Ogbeni Niyi Ojo ati awon miran ni won ta ko ohun ti Fayose se yii. Won ni o lodi pata-pata si alaale egbe PDP. Won ni ko si ninu iwe ofin egbe ki awon maa gbe eni kan le awon oludije to ku lori. Won ni ofin egbe ni ki gbogbo awon to ba nifee si ipo bo si gbangba lati dan gbajumo won wo, ti won ba ti yege alaale egbe.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…