Home iroyin Eto Isinku Faleti: Ijoba Ipinle Oyo fun ebi oloogbe ni N5m
iroyin - September 6, 2017

Eto Isinku Faleti: Ijoba Ipinle Oyo fun ebi oloogbe ni N5m

Moroof Azeez Olalelkan

Ijoba Ipinle Oyo ti fun ebi osere pataki, Oloogbe Adebayo Faleti, ni milionu marun-un naira fun eto isinku re to n lo lowo.

Komisanna Eto Asa, Alagba Toye Arulogun, lo fi iwe owo naa jise fun ebi oloogbe, ni ile re to wa ni agbegbe Ojoo ni Ibadan.

Arulogun ni ijoba Abiola Ajimobi mo riri ipa ti Faleti ko ninu idagbasoke eko ati asa ni Ipinle Oyo ati Naijiria lapapo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…