Isonu kuro lori Odunlade Adekola, Bukola Adeeyo fi eni to bimo fun han
Enu opo eniyan to n so pe Odunlade Adekola ni baba omo osere fiimu asesejade, Bukola Adeeyo, yoo wa wo wowo bayii, latari bi arabinrin naa se siso lo eegun.
Nigba to sese bimo si ilu oyinbo, baba omo re ko yoju jade.
Awon eniyan war o pe Odunlade lo wa nidii oro ni, paapaa tori bi won se sun mo ara won to lenu ise fiimu.
Nigba ti Bukola naa yoo je ki oro tubo ta koko, ko fi oju baale re naa han.
Sugbon o ti se eyi bayii.
Oruko re ni Bello Oladipo Ibraheem, ti oun naa je osere fiimu ti won saaba maa n pe ni OmobaSanjay, to si je pe ore Odunlade ni.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…