Ikunle abiamo! Omo yunifasiti ku iku ojiji
Ibanuje nla ti sele ninu ebi omo ile iwe kan tele, Adegboyega Adeyinka Khalid, tori pe oniwaju ti keyin, ti eleyin si siwaju.
Omo ile eko Ondo State University, Okiti-Pupa ni Adeyinka je tele, to n ko eko nipa ise ogbin eja.
Omo olodun keji (200 levels) ni ki olojo to de.
A gbo pea are ko fi bee s e tele.
Okan lara awon ore re so pe o kan so pe orun n dun oun ni, ti won sig be e digbadigba lo si osibitu.
Ibe naa lo ku si.
Ki Olorun duro ti awon obi re.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…