Home LÁGBO ÀRÍYÁ Foto iya Alabi Pasuma bad gan-an!
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 5, 2017

Foto iya Alabi Pasuma bad gan-an!

 

 

Ti awon omo ode oni ba ri nnkan kan to dara gidigidi, won a maa so pe ‘O bad gan-an!’

O seese ki iru awon eniyan bee so nnkan kan naa ti won ba ri foto iya osere fuji pataki, Wasiu Alabi Pasuma, kan to sese gbe sori afefe.

Ninu foto naa, iya naa wo aso olowo nla to dara, o le igo kan to le mo oju, ti gbogbo ara re si fihan pe idunnu ati ibale okan joba laye re.

Pasuma gbe foto naa jade lati fi se eye fun iya naa to n se ojo ibi re.

Akorin naa wa ki iya naa ni mesan-an mewaa.

O ni oun dupe fun bi o se je oloko to wa oun waye. Pasuma ni oun dupe lori ife ododo ti iya naa ni si oun. O ni nigba ti ko tii si nnkan kan, iya naa lo duro ti oun. O wa fi kun un pe iya oun ni ‘best mum in the world’, iyen, iya to dara ju ni gbogbo agbaye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…