Home LÁGBO ÀRÍYÁ Eucharia Anunobi fi posi olowo nla sin omo re to ku
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 5, 2017

Eucharia Anunobi fi posi olowo nla sin omo re to ku

 

Rita Dominic, Monalisa ba a daro ni iboji

Ojo malegbagbe ni oni je fun osere fiimu to ti di pasito bayii, Eucharia Anunobi, tori pe oni ni won sin oku omo kan soso to bi.

Omokunrin naa, ti oruko re n je Ekwu, di oloogbe laipe yii, to si je pe arun aromoleegun sickle cell lo pa a.

Opo awon osere jankan-jankan lo lo ba Eucharia daro.

Lara won ni Rita Dominic ati Monalisa.

Lati wa fi ife ti iya omo naa ni si i han, ati lati fi asa awon igbo han nipa sinsin e I to ba sun mo won, kibaa je omode, posi to n tan yinrinyinrin ni won gbe Egwu si, eyi to ma je olowo nla.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…