Home Orisirisi Pasitọ kọ̀ láti so obìnrin yìí pọ̀ lọ́jọ́ ìgbéyàwó
Orisirisi - September 4, 2017

Pasitọ kọ̀ láti so obìnrin yìí pọ̀ lọ́jọ́ ìgbéyàwó

Pasitọ kọ̀ láti so obìnrin yìí pọ̀ lọ́jọ́ ìgbéyàwó

Yoruba bo won “ko si bi a se maa daruko aja ti won ko ni daruko ikoko ti won fi see”. Eyi lo mu ki ojise Olorun kọ lati so arabinrin pọ mọ ẹni to pe ni ọkọ rẹ lọjọ to yẹ ko jẹ ọjọ ẹyẹ wọn.

Ọjọ yii pada di ọjọ abamọ fun iyawo ati awọn eniyan rẹ. Abi ẹẹ rii pe “were dun un wo, ko see bi lọmọ ni”.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…