Mo setán láti pa ẹni tó bá fọwọ́ kan ìyàwó mi- Baba Adeboye
Leyin n ose meji ti Olori ijo Ridiimu, Pastor E. A. Adeboye, kiisi iyawo re, Pator Adeboye ni ita gbangba, ojise Olorun naa ti fi oba le e o.
O ti wa so bayii pe oun setan lati pa enikemi to ba fowo kan obinrin naa.
O so lasik to n waasu lojo Sunday pe bi oun ko ba ti sa our eni bee ladaa, oun yoo gbadura si Olorun pe ki o sun ko ma ji mo laelae.
Baba Adeboye so eyi lati fi ife to ni si iya naa han ni.
O ti d aadota odun ti won ti fe ara won.
Ojise Olorun na ro awon lokolaya ki won maa fife lo nigbakuugba.
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…