Home Orisirisi Ìsàlẹ̀ ọrọ̀ lẹ́gbin! Ìgbẹ́ onígbẹ̀ẹ́ ni Clement ń kó jẹ nítorí owó
Orisirisi - September 4, 2017

Ìsàlẹ̀ ọrọ̀ lẹ́gbin! Ìgbẹ́ onígbẹ̀ẹ́ ni Clement ń kó jẹ nítorí owó

Ko si ohun ti oju ko ni ri ni orileede yii, ni nnkan bii odun meji seyin bayii ni owo te okunrin kan to n ko igbe arabinrin kan je ni ori akitan to daa sii, ilu Akuku ni ipinle Edo ni isele naa ti sele. Obinrin naa da igbe nu lo ba boju weyin to ri okunrin naa pelu buredi lowo, to si n fi igbe naa ra buredi bii bota. Eyi lo mu ki o pariwo sita ti awon eniyan si ran an lowo lati mu eni naa. Nigba ti owo nina dun un, o jewo pe oogun owo ni oun fe fi se ati wi pe obinrin ti o ni igbe naa maa kuku ojiji ti won ba je ki oun ri igbe naa je tan.

Ose to koja ni owo tun te odomodekunrin ti oruko re n je Junior Clement, omo bibi ilu Warri ni ipinle Delta. O ni eleekeji niyii ti oun maa ko igbe je. O ni babalawo ni oun ko see bi o ti ye ki oun se ni ko je ki o di owo fun oun ni akoko, eleekeji naa tun ni won tun ka oun yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…