Home Orisirisi Ikú ń rùn lórí ọkùnrin tó bá súnmọ́ obìnrin tó bá kọ ọba sílẹ̀ – Yemi Elebuibon
Orisirisi - September 4, 2017

Ikú ń rùn lórí ọkùnrin tó bá súnmọ́ obìnrin tó bá kọ ọba sílẹ̀ – Yemi Elebuibon

Ogbontarigi elesin  Ifa, Araba  Yemi  Elebuibon, ti  se  kilokilo  pe  enikeni  to  ba  fe fi  obinrin  to  ba  ko  oba  Yoruba  sile  n fiku  rumu.

O ni bi ko ba  sora  too lo  si  ajo  aide, tabi  ki  Asian buruku de ba a lalejo, tabi  ki  ajalu fi odede re  se  ibugbe.

O so eyi nigba ti o n ba  awon  oniroyin  soro  lori bi ipinya se de  laarin Ooni  Ife,  Oba Adeyeye Ogunwusi, ati Olori re tele, Wuraola Zynab Etiti.

Elebuibon ni ki obinrin kankan  to  le  gori  our obinrin bee, o gbodo return gidi gid.

i

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…