Home Orisirisi Àwọn Dókítà bẹ̀rẹ̀ ìyansẹ́lódì
Orisirisi - September 4, 2017

Àwọn Dókítà bẹ̀rẹ̀ ìyansẹ́lódì

Oni ojo kerin, osu kesan-an ni awon Dokita to n sise fun ijoba ni ipinle ati ti ijoba apapo bere iyanselodi.

Won ni awon ti wa lori aroye lati odun 2013, ti ijoba si ko lati kobi ara si aroye awon. Gbogbo awon ile iwosan ijoba ti awon oniroyin se abewo si ni won ti darapo mo iyanselodi naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…