Àjẹkún ìyà ni Cameroon jẹ lọ́wọ́ Naijiria
Ojo jimo, ojo kinni ni Orileede Naijiria waa ko pelu akegbe won ni Cameroon ti Naijiria si ba won wi bii igba ti baba n ba omo re wi pelu ami ayo merin si odo, ni ilu Uyo.
Abala keji lo waye ni Younde ni orileede Cameroon, Naijiria ni o koko ye oju ile won wo ki awon naa to se bi eni fowo fa, bi eni faya wo pelu penariti lati le gba eyokan tiwon naa wole.
Eyi tumo si pe Cameroon tun je ajekun iya nitori bii eyo meji ni eyokan ti Naijiria gba wole won ti eyokan tiwon ko kuro ni eyokan. Idije toni je ki ati kopa ninu idije ife agbaye “World Cup” rorun fun Naijiria.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…