IKÚ PA PRINCE ADEKUNLE!
Iku doro o pa PRINCE Adekunle,
Akoni onijuju se bee o jade laye.
Iku woke ere, iku woke, o mu oba orin lo
Omo Slate e ku irony
Prince Adekunle se bee o waja!
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ
Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…