Home Orisirisi Ajimobi sìrègún sí Olubadan, àwọn ènìyàn kan fàbínú yọ
Orisirisi - September 3, 2017

Ajimobi sìrègún sí Olubadan, àwọn ènìyàn kan fàbínú yọ

Aawo to wa laarin Gomina Abiola Ajimobi ti Ipinle Oyo ati  Olubdan ti Ibadan, Oba Saliu  Adetunji si  n  feju sii  ni  o.

Lasiko ti Ajimobi n soro lori redio ni Ibadan, o ni ko ye  ki Olubadan maa huwa lodi si oun tori ogorun milionu naira  ni oun na nibi ayeye ati gbe ade le Olubadan lor.

Sugboni eyi ti mu ki  awon eniyan kan maa binu si gomina.

Wob ni  ko ye ki o maa  siregun si oba alaye naa tori pe kii se owo ara re lo na, owo ilu ni.

Lara  awon to ti fi ehonu han ni Ogbeni Tunde Aremu, to je oga oniroyin ati osise idagbasoke ilu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́

Adédoyin ṣépè fáwọn oníròyìn nílé ẹjọ́ Ọrẹ Òtítọ́jù Ìyàlẹ́nu ló jẹ́ fáwọn oníròyìn láàárọ̀…