Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Victor Moses rántí ikú òbí rẹ
ERÉ ÌDÁRAYÁ - September 2, 2017

Victor Moses rántí ikú òbí rẹ

Irole ana ojo Jimo ojo kinni, osu kesan-an ni orileede Naijiria gbo ewuro ayo merin si odo wole alatako won, orileede Cameroon. Victor Moses ni o gba boolu keta wole Cameroon peluu opolopo ise asekara lati ran awon goo toku lowo.

O pari ise yii fun orileede Naijiria ni o wa ranti pe orileede yii kan naa ni o seku pa awon obi oun mejeeji ninu ija ilu Kaduna.

Eyi lo mu ki Mikel Obi ati awon agbaboolu to ku maa parowa sii. Awon eniyan woo pe nise lo ye ki inu won maa dun nitori pe ami ayo kan ti won ba gba wole je milionu marun-un naira.;

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…