Home Orisirisi Spiritual battle: Ẹgbẹ̀rún esinsin wọlé lọ bá ọmọ Tonto Dikeh nínú yàrá
Orisirisi - September 2, 2017

Spiritual battle: Ẹgbẹ̀rún esinsin wọlé lọ bá ọmọ Tonto Dikeh nínú yàrá

Osere fiimu, Tonto Dikeh, ti ke gbajare pe awon ogun airi kan n ba oun ja.
O ni awon ogun esu naa ko sese bere, paapaa leyin ti ija sele laarin oun ati bale oun tele.
O ni eyi to buru ju ni pe igba ti oun wonu yara ti oun gbe omo oun si, oun ba esinsin bii egberun nibe.
Tonto Dikeh ni ko si ohun kankan to ra, to sedin tabi ti o n run ninnu yara naa, debi pe o le fa esinsin wole.
Bakan naa, o ni kii se igba akoko ti iru re maa sele.
O wa kegbe lohun rara si Olorun oba; o ke bi abiamo ti idaamu ba de ba se maa n ke, to si so pe ibi yowu ti ibi naa ba ti wa, o maa lo re ba onibi ni.
Koda, aanu abiamo yoo se eni to ba ka ohun pataki to ju sita lori ero alagbeeka, tori o so debi pe to ba ku ki oun fie mi ara oun sile ki ti omo oun le duro, oun ko nii ko.
Adura wa si oba oke nip e ogun idaamu ninu ile re, ati ninu ile eni kookan wa yoo di sise.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…