Ọlọ́run tóbi l’Ọ́ba! Awakọ̀ jáde láì farapa nínú mọ́tò tí àjàgbé ejò yí lé lórí
Eni Olorun ko pa ko ku! Gege bee ni ti arakunrin to duro yii.
Eyin e wo foto moto ajagbe ejo yi, ati moto ayokele to wa labe re. Tanka naa ja lu moto naa lori ni lasiko ti okunrin yii n wa ayokele naa lo.
Sugbon alagbara ni Olorun! Nnkan kan ko se okunrin yii, to si n dupe lowo Olodumare kikankikan. Koda, awon ti won gbagbo ninu oogun n ro pe nnkan miiran wa nibe ni.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…