Home Orisirisi Ohun tó fa ìpínyà láarin èmi àti ìyàwó tí mo kọ́kọ́ fẹ́ – Adewale Eleso
Orisirisi - September 2, 2017

Ohun tó fa ìpínyà láarin èmi àti ìyàwó tí mo kọ́kọ́ fẹ́ – Adewale Eleso

Ogbontarigi apanilerin-in osere, Alagba Adewale Eleso, ti so idi ti oun ati akofe iyawo re se pinya.

Eleso je osere kan ti kii ko obinrin kaakiri bi awon elegbe re miiran.

Koda, nigba ti awon alariya miiran ni iyawo bii meta merin ati ju bee lo, iyawo kan soso naa lo wa loode Eleso bayii.

Bee, iyawo mejo ni baba re ni ko to di pe olojo de.

Ninu iforowanilenuwo kan pelu Eleso, o se alaye pe obinrin re akoko naa pinnu pe oun fe lo si oke okun, nibi to fe maa gbe.

Eleso ni oun wa so fun un pe bi o ba ti se bee, a je pe o di baibai niyen, tori oun ko nigbagbo ninu ife okeere.

Idi niyi ti osere naa fi fe iyawo to w anile re bayii.

Eleso salaye pe Oke Ara, ni Ile-Ife, ni won bi oun si. O ni agbegbe ibe naa ni un ti lo si ile-iwe alakobere ati Modern School, ki oun to bere ise oogun tita, eyi ti a mo si chemist.

O fi kun un pe igba ti awon olopaa n da ohun laamu ni oun fi ise naa sile, ki Olorun to wa dari ese re si ere tiata ati fiimu sise.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…