Pasuma ki awon ololufe re ku odun
Osere fuji pataki, Alhaji Wasiu Alabi Psuma, kan si awon tie laaro oni.
O ki won ku odun, to si gba a ni adura ki Olorun o je ki odun o yabo.
Eyi lo fa a ti opo eniyan naa fi fi idunnu da a lohun, ti won n sa a ni mesan-an, mewaa.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…