Home iroyin Págà! Suleiman pa ènìyàn méjì níbi tí wọ́n ti ń kírun Iléyá ní Ìjẹ̀bú Igbó
iroyin - September 1, 2017

Págà! Suleiman pa ènìyàn méjì níbi tí wọ́n ti ń kírun Iléyá ní Ìjẹ̀bú Igbó

Isele buku kan se ni ilu Ijebu Igbo lonii, nigba ti awon Musulumi n kirun Ileya lowo.

Arakunrin kan, ti won pe oruko re ni Ope Suleiman, to n wa moto ti won fi ko pako, ni o fa laasigbo naa.

A gbo pe ijanu (brakes) moto jagi to wa lo ja bute, ti moto naa si ja lu awon to n ki Yidi lowo.

Bayii ni o se pa eniyan meji, ti won si so pe olopaa kan naa tun ku nigba ti wahala sele.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…