Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Náìjíríà na Cameroon ní ayò mẹ́rin sódo ( 4-0): wọ́n tún ní “Àjẹkún ìyà ni Cameroon ó jẹ”
ERÉ ÌDÁRAYÁ - September 1, 2017

Náìjíríà na Cameroon ní ayò mẹ́rin sódo ( 4-0): wọ́n tún ní “Àjẹkún ìyà ni Cameroon ó jẹ”

Orin yii ni o gbenu awon agbaboolu Super  Eagle ti orileede Naijiria ni igba ti won waa ko pelu iko agbaboolu Indomitable Lion ti orileede Cameroon. Ere boolu naa waye ni Uyo ni ipinle Akwa Ibom ni ojo Jimo, ojo kinni, osu kesan-an odun yii.

Ami ayo meji ni Naijiria gba wole ni abala akoko, Ighalo ati Mikel lo gba meji akoko wole ni igba ti Vicyor Moses ati Ihanancho gba meji tiwon naa wole ni abala keji.

Ayo merin otooto yi je ibanuje gidi funawon agbabollu yi nitori ileri ati naa iko Super Eagles ni won gbe wa si orileede Naijiria.

Ojo monde, ojo kerin osu yii ni awon iko Naijiria maa lo gbaa ti orileede Cameroon ni eyi to maa fi agba han daadaa ninu iko mejeeji, bi o tile je pe orin ajekun iya ni Naijiria n ko fun awon iko Cameroon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…