Home Orisirisi Fayose we lawani babatutu lojo Ileya
Orisirisi - September 1, 2017

Fayose we lawani babatutu lojo Ileya

Ti won ba n wa gomina to je alara gbayida, ilu Ado Ekiti ni ki won lo.

Gomina Ayodele Fayose lo si n je bee. O tun se kasiara kan lonii, nigba to we lawani babatutu lo si Yidi, nibi ti awon Musulumi ipine naa ti lo yombo Olorun.

Elesin Igbagbo ni Fayose, to si je pe ojise Olorun ni iyawo re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…