Home Orisirisi Araparegangan ki Yidi ni Abeokuta
Orisirisi - September 1, 2017

Araparegangan ki Yidi ni Abeokuta

 

O to ojo meta ti opo eniyan ti ri osere fiimu pataki, Kabirah Kafidipe, iyen Araparegangan gbeyin. Iru awon eni bee to wa ni Abeokuta ni anfaani ati se alabapade re ni owuro yii.

Eyi sele ni Yidi, nigba ti oun naa dara po mo awon Musulumi lati lo sin Allah fun ti odun Ileya.

Kabirah ati awon ebi re, to fi mo egbon re Aishat, ati iyaami re ni won jo wa ni yidi.

Arapa wo kaba to bale to mo lolo, to wa fi iborun funfun le e lori.

Omo Abeokuta ni osere naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…