4 – 0! Nigeria sọ Cameroon di dìndìnrìn ní Uyo
Egbe agbaboolu Super Eagles ti so akegbe won lati Cameroon di suegbe patapata o.
O ku ki iseju mejila ki idije to n lo lowo ni papa isere Uyo pari, sugbon Super Eagles ti gba ami ayo merin wole Cameroon.
Odion Igbalo gba akoko wole, nigba ti Mikel,, Victor Moses ati Ihenacho naa fi oba le e.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…