Oro ko tii to so bayii lori Wuraola – Ooni
Ooni ti Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi ti so pe oun ko nii ti fesi lori ohun to sele laarin oun ati Olori re tele, Wuraola Zynab Etiti, to fi di pe o ko kuro laafin.
Ooni ni ojo oro n bo lona.
Ana ni Wuraola so fun gbogbo agbaye pe gberu ti ke, oun ti ko jade ni aafin, ati pe ko si ajose mo laarin oun ati Kabiyesi.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…