Idi ti mo fi n lo foonu meje – Dele Momodu
Opo omo Naijiria ni enu ya laipe yii nigba ti won ri i pe foonu meje ni oludasile iwe iroyin alariya OVATION, Alagba Dele Momodu, n lo.
Koda, awon kan so pe aye alabaka lo n je.
Sugbon okunrin naa ti da won lo’hun, o ni aimokan lo n ba won finra.
O ni loooto ni oun n lo foonu meje, sugbon kii se tori afeaye.
O ni irin ise oun ni, tori okookan awon foonu naa lo ni ise to n se.
Momodu ni foonu kan wa fun awon ti oun n ba soro ni orile-ede kookan, tori ise oun je mo bee.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…