Orisirisi - August 31, 2017

Kin ni Olu Falaye fi se awon Fulani darandaran gan-an?

Yoruba bo won ni a kii gbe’le eni ka f’orun ro. Sugbon ohun to ti n sele si okan lara awon agba Yoruba, Oloye Olu Falaye, lati odun bii meji seyin ko lo ni ilana ofin yii o.

Leyin pe oloselu ati onimo ijinle nipa owo ni Falae, o tun je agbe alada nla.

Sugbon awon alakatakiti darandaran Fulani ko yee ba a finra.

Awon Fulani naa n da maalu wo inu oko re, ti won si n ba nnkan olowo iyebiye je.

Awon Fulani naa lo ji i gbe nigba kan.

Ni ojo bii merin seyin, won tun da maalu wo inu oko Faleye, ti won sit un da ibanuje nla si i nigba.

Latari eyi, IROYIN OWURO n beere: Kin ni Falye se fun awon Fulani darandaran gan-an?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…