Home iroyin Ọwọ́ ba olè tó jí ẹran Iléyá gbé
iroyin - August 30, 2017

Ọwọ́ ba olè tó jí ẹran Iléyá gbé

Olorun Oba oga ogo ko fi nnkan kan ni omo araye lara. Olorun ko so pe ki eni kan se oun ti apa re ko ka ninu esin, koda ko so pe bi Musulumi ko ba lagbara lati pa eran odun, o gbodo pokunso tabi ko so ara re di igara olosa. Kin lo wa sele si okunrin yii to fi lo ji eran gbe o?
Foto isele naa sese jade ni, nibi ti o ti n gbe eran naa digbadigba kaakiri nigba ti owo te e.
Bi o tile je pe a ko tii mo oruko re, Ipinle Osun ni won so pe o ti sele.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

OTOLORIN YORUBA: Itumo owe ‘Omo go, e ni o ma ku, pelu FIDIO

Okan lara awon owe Yoruba pataki ni ‘Omo go, e ni ko ma ku, kin lo tun n pa omo to j…