Home iroyin Olùgbée Makurdi rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba àpapọ̀
iroyin - August 30, 2017

Olùgbée Makurdi rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí ìjọba àpapọ̀

Awon olugbe ilu Makurdi ni ipinle Benue lo n ke gbajare si ijoba apapo ko dakun gba awon lowo omi to ko ti ko fa mo lati ijeerin ti ojo ibanuje naa ti ro.

Won se afihan bi omi se wo inu ile ti Eledua si ko won yo nipa lilo awon ara adugbo lati maa wo ile ni okookan lati doola emi awon olugbe ilu naa.

“Kaka ki ewe agbon de, pipele ni o tun n pele sii” ni oro omi naa, ni eyi to ka awon ara ilu naa laya. Won ni gbogbo nnkan ini awon ni awon ti fere padanu tan si owo omiyale naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…