Magu jẹ́wọ́ iye owó tí àjọ EFCC rí gbà
Adele Aare ajo EFCC to n moju to awon to n ko owo ilu je, Ibrahim Magu se atejade iye owo ti won ti ri gba lowo awon ara ilu lati bii osu mejo ti won ti n sode awon onijibi kiri.
Apapo owo ile Naijiria je bilionu mesan-an le ni oodunrun (N409) nigba ti owo ti ile okeere je Dola mokandinlaadota ($49).
Magu ni “ojo si n ro ni o, ko tii da ni eyi ti ko ni je ki a le so pe ko to ti ana”. O ni awon si n te siwaju nipa sisode awon onijibi ile Naijiria.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…