Home iroyin Ládọjà sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí Ajimobi lórí àwọn ọba tuntun
iroyin - August 30, 2017

Ládọjà sọ̀kò ọ̀rọ̀ sí Ajimobi lórí àwọn ọba tuntun

Gomina Ipinle Oyo nigba kan, Oloye Rahidi Ladoja, ti so oko oro si Gomina Abiola Ajimobi lori bi o se gbe ade fun awon oba mokanlelogun miran ni Ibadan.
Ladoja wa lara awon ti Ajimobi fe so di oba sugbon o ni oun ko fe, o si ti gbe gomina lo si ile ejo.
O ni igbese ti Ajimobi gbe fe so oye olubadan di yeye, .
O ni aye alabaka ni Ajimobi n je, to si hu iwa ta ni yoo mu mi.
O wa fi kun un pe oun mo pe laipe, otubante ni kinni naa yoo ja si.
Ninu atejade kan ti Ladoja gbe sita, o ni o ya oun lenu pe Ajimobi ko fun awon asofin Ipinle Oyo laaye lati se agbeyewo asa ati ofin lobaloba Ibadan ko to di pe o gbe ade rere jade.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ

Rògbòdìyàn ẹgbẹ́ onímọ́tò Èkó n fẹ́jú kẹkẹ Ọrẹ Òtítọ́jù Àwọn àgbà sọ pé ìjàngbọ̀n kìí nìka…