Home Orisirisi Iro ni won pa mo mi, n ko se agbere ni aafin Ooni – Olori Wuraola
Orisirisi - August 30, 2017

Iro ni won pa mo mi, n ko se agbere ni aafin Ooni – Olori Wuraola

.O ni loooto ni igbeyawo awon ti fori sanpon

Oro ija to wa laarin Ooni Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, ati Olori Wuraola, to ti n lo ni abenu tele, ti wa ja si ita gbangba bayii o.

Iyaafin Wuraola ti soro, o ni loooto ni igbeyawo naa ti daru patapata.

O ni oun ti ko kuro laafin, ti oun si ti bere igbe aye miiran.

Sugbon sa o, ninu atejade pataki kan to gbe sori ero alatagba, Wuraola ni iro ni awon to so pe oun se agbere ni aafin n pa.

O ni ko si ohun to jo bee. O ni kii se nnkan rere bi won se maa n paro mo obinrin nigba ti igbeyawo ba daru.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…