Home iroyin Ìmọ̀ràn FRSC ní ọ̀nà Èkó sí Ìbàdàn
iroyin - August 30, 2017

Ìmọ̀ràn FRSC ní ọ̀nà Èkó sí Ìbàdàn

Awon ajo to n mojuto lilọ bibọ ọkọ ni ọna arinye ti gba awon ara ilu agbegbe Eko ati Ogun nimoran lasiko odun Ileya yii.

Ajo yii ran wa leti pe odun ileya bo si ojo Jimo, ojo kinni osu kesan, odun yii nigba ti ipago olosoosu ti ijo Redeeemed naa bo si ojo kan naa. Ijo MFM naa ni ipago ti won pe ni “Power must change hand” ni ojo keji osu kesan-an, nigba ti gbaju-gbaja odun “ojude oba” ti o wa ni Ijebu ode naa maa waye ni ojo keta, ojo sonde.

Ojo meteeta ni ona kan naa ni o je ki awon ajo yii maa gba ara ilu nimoran ki o le baa ro teru-tomo lorun.

Won tile se akajuwe awon ona bii – Sango Ota si Ifo, Sagamu si ijebu-ode, Ijebu-ode si Benin, Mowe-Ofada si Sagamu ati bee bee lo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…