Home iroyin Aare Buhari lọ ilé ọdún
iroyin - August 30, 2017

Aare Buhari lọ ilé ọdún

Yoruba bo , won ni “erin ko yato to fi de ilu Oyinbo, eni to ba kawo lori, ekun lo n sun”. Eyi lo difa fun Aare Muhammadu Buhari ti oun naa fi digba di agbon to si gba ilu re lo ni Daura, ipinle Katsina lati lo sodu Ileya.

Eleran ara naa kuku ni Aare Buhari, eyi lo mu ki oun naa te oko leti lati lo sodun pelu ebi re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…