Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ọmọ Iyabo Ojo tọrọ àforíjìn lọ́wọ́ rẹ
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 29, 2017

Ọmọ Iyabo Ojo tọrọ àforíjìn lọ́wọ́ rẹ

 

 

Omo bibi inu onifiimu Iyabo Ojo, iyen Priscilla, ti ko leta pataki kan si iya re, nibi to ti toro aforijin.

Ninu leta naa to fi si ori ero alatagba, omo naa ni ki iya oun f’ori jin oun lori wahala yowu ti un ti ko o si.

Pricilla ko so pato boya ese kan wa to loorin ti oun ti se iya oun, sugbon o ni ko saa fi tokantokan dari jin oun.

O tun wa dupe lori oore nla-nla ti iya maa n se fun omo, eyi to ni iya oun ti n se fun oun lati ojo ti oun ti daye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…