Olubadan yan fanda káàkiri ọjà, àwọn ọmọ Ibadan sùùrù bò ó
Olubadan ti ile Ibadan, Oba Saliu Adetunji, ti fihan pe oun si wa ni ipo awon baba nla oun lai fotape.
Ojo keji ti Gomina Abiola Ajimobi gbe ade le awon oba mokanlelogun miiran lori, Olubadan dude fuya, o bo sinu moto re, o si yan fanda lo si oniruuru oja ni Ibadan.
Nibe ni opo awon ara ilu ti n suuru bo o, ti won pariwo idunnu, ti won si n so pe oun ni oba ti awon.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…