Home iroyin Ìyàwó mi kò jẹ́ kí n bá òun sùn! Kolade Atanda pariwo nílé ẹjọ́
iroyin - August 29, 2017

Ìyàwó mi kò jẹ́ kí n bá òun sùn! Kolade Atanda pariwo nílé ẹjọ́

 

 

Arakunrin kan to fi ilu Ibadan se ibujokoo, Ogbeni Kolade Atanda, ti gbe iyawo re, Dupe Atanda lo si ile ejo kan ni Ojaaba ni Mapo, o.

O fi esun kan obinrin naa pe o n fi atilaawi dun oun.

O ni obinrin naa kii fun oun laaye ti oun ba fe sere ife pelu re.

O ni asiko ti oun ba so fun un pe ki o je ki awon wo yara lo ni yoo bere sii gba adura.

Kolade tun fi kun un pe iya iyawo oun tun n da kun wahala awon, to si je pe Dupe n gbe omo oun sa fun oun.

Nipa bayii, o ni ki Adajo Ademola Odunade tu igbeyawo awon ka.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…