LÁGBO ÀRÍYÁ - August 29, 2017

Funke Akindele, Opeyemi Ayeola di omo ogoji odun nigba kan naa

O ti wa f’oju han gedegbe bayii pe ose kan pere ni Funke Akindele-Bello fi ju Opeyemi Ayeola lo.

Asiko kan naa ni irawo awon mejeeji tan jade ninu ise fiimu, bi o tile je pe Opeyemi ko fi gbogbo ara kopa ninu fiimu mo.

Lati igba to ti se igbeyawo lo ti kolo si ilu oyinbo, nibi ti Olorun ti yonda omokunrin meji lanti-lanti fun un.

Oni ni obinrin naa pe ogoji odun laye, ti inu re si n dun sinkin, to n sosoro jininle, to si n dupe lowo Oluwa.

Ose to lo ni Funke naa pe omo ogoji odun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…