Orisirisi - August 28, 2017

N ko ko iyan Olubadan kere – Ajimobi
Bi igbese ti Gomina Ipinle Oyo, Senito Abiola Ajimobi, gbe nipa atunto loba-loba Ibadan se n ru opo eniyan loju, gomina naa ti so pe oun ko nii lokan lati gun Olubadan gaagaa.
O ni ijoba oun gbe oba mokandinlogun miiran dide lati mu ilosiwaju ba ilu ni.
O ni igbese naa yoo tubo mu ki ipo Olubadan o gberu sii ni, tori oun naa si ni olori gbogbo awon oba naa.
Sugbon opo awon eniyan, paapaa awon omo Ibadan ni oro naa si toju su, ti kaluku si n jarankan lori re.
Ohun to toju su won ju ni ti awon oloye Olubadan tele ti awon naa ti di alade lori, bee won ko ni ilu kan pato ti won joba tiwon le lori.ium wp-

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu

Bí ẹgbẹ́ òṣèlú ù mi bá fàmí kalẹ̀, ìyókù sẹ́pẹ́rẹ́—Tinubu Ọrẹ Òtítọ́jù Olùdíje fún i…