Ogbon oba loojo: Olubadan ko yoju si Mapo
Aawo to wa laarin Gomina Abiola Ajimobi ati Olubadan ti Ibadan, Oba Saliu Adetunji, de oju gongo lonii, nigba ti Kabiyesi fi aake kori ti ko yoju si Mapo, nibi ti ijoba Ipinle Oyo ti gbe ade le ogbon oba miiran lori.
Olubadan ko fara mo igbese Gomina, o si so pe ti won ba ri ese oun nibi aseye naa, ki won ge e.
Oba naa se bi o se so, tori ko ba won yoju sibe.
Ohun ti yoo sele laarin awon mejeeji leyin tonii, Olorun lo mo o.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…