Home iroyin NÍ’BÀDÀN:Láálà yóò lu lónìí, aruputu yóò hu!
iroyin - August 27, 2017

NÍ’BÀDÀN:Láálà yóò lu lónìí, aruputu yóò hu!

Ti ariran kan ba so asotele ni odun to  lo pe ni odun 2017 yii,  ade yoo di mokanlelogbon ni Ibadan,  opo eniyan yoo so pe iro ni.
Sugbon lonii,  ni Ibadan nile Oluyole, nibi ole gbe n jare olohun; Ibadan ilu Ojo, Ibadan ilu Ajayi,  Ibadan ilu Ogunmola Olodogbo Keri logun, ijoba Abiola Isiiaka Ajimobi yoo gbe ade le ogbon baale ati awon oloye lori!
O kasiara!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…