Me and my Husband: Mosun Filani tele oko re lo sidi oselu
Laarin Mosun Filani ati oko re, Alagba Kayode Oduoye, bi igbin ba fa ikarahun a tele e ni. Eyi naa lo fa a to fi je pe arabinrin osere fiimu naa ti fee di oloselu tan.
Baale re wa laarin awon to fe du ipo gomina ni Ipinle Osun.
Nipa bee, Mosun naa ti n se kuku-keke, to si n seto bi baale re yoo se r’owo mu ninu oselu.
Ti a ko ba gbagbe, Ipinle Osun naa ni onifiimu Kayode Makinde ti dide to fi wole si ile igbimo asofin Abuja.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…