Home LÁGBO ÀRÍYÁ Is Gaju! Orin wo ni Epo Akara ko ba ko n’Ibadan loni?
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 27, 2017

Is Gaju! Orin wo ni Epo Akara ko ba ko n’Ibadan loni?

 

Pelu bi ijoba Abiola Ajimobi se gbe ade fun ogbon oba miiran ni ilu Ibadan lonii, orin wo ni olorin pataki ni ilu naa nigba kan, Dauda Akanmu Epo Akara baba Tawakalitu,  ko ba ko to ba je pe o wa laye ni?

Ko si aniani pe kiba korin fun o kere ju eni kan laarin awon oba tuntun, tabi Gomina Abiola SAjimobi tabi Olubadan!

Boya orin IS GAJU ni o, O BEAUTIFUL ni o tabi ARA MEERIRI, mo rire l’ona oja!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…