Baálé mi fẹ́ràn ilá alásèpọ̀ – Funmi Aragbaye
Akorin emi ti a mo si Funmi Aragbaye ti so asiri ohun to je
ki ife to wa laarin oun ati oko re ko larinrin.
Odun 1977 ni won ti se igbeyawo, leyin ti won ti jo jade fun odun meta, eyi ti awon oloyinbo n pe ni courtship.
Ninu iforowanilenuwo kan, akorin naa ni awon nifee ara awon denu.
O ni bi ikunsinu ba wa awon jo maa n be ara awon.
O fi kun un pe bi ija ba waye laarin awon, eyin baale oun ni iya oun maa n wa.
Bakan naa, Funmi Aragbaye, eni to ko orin IRI ORUN SO KALE, ARAYE E YIPADA… so pe ibowo ti oun ni fun oko oun kii je ki oun maa fi ise kisinni ati ise ile miran lo o.
O tun wa tu asiri iru obe ti baale re feran julo.
O ni ILE ALASEPO ni!
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…