Home Orisirisi Restructuring: Obasanjo tako awon agbaagba Yoruba to n ja fun atunto Naijiria
Orisirisi - August 26, 2017

Restructuring: Obasanjo tako awon agbaagba Yoruba to n ja fun atunto Naijiria

 

Opo eniyan lo maa n so pe Aare ana, Oloye Olusegun Obasanjo, maa n gbe leyin awon Hausa/Fulani ti ariyanjiyan ba sele laarin awon ati Yoruba.

Iru awon eniyan bee tun ti ni anfaani lati pe  Obasanjo ni ota Yoruba bayii, latatri bi o se so pe oun ko fara mo atunto Niajiria, ti awon oloyinbo n pe ni restructuring.

Opo awon agbaagba ati onimo Yoruba lo wa nidii ipe fun atunto naa, sugbon Obasanjo ti so pe oun ko fara mo o.

O ni opo awon to n soro ‘restructuring’ naa fi ete sile, ti won n pa lapalapa.

  • O ni enu won ko ko. O ni dipo atunto Naijiria, atunto okan awon omo orile-ede yii lo ye ki a wa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…