Liz Anjorin kan sile lati Mecca
Osere fiimu, Liz Anjorin, wa ni Mecca lowolowo bayii, nibi ti o ti n kan si omo Naijiria, to n so pe oun dupe lowo Olorun.
Awon osere fiimu bii Dayo Amusa ati Fathia Balogun naa lo si ilu nla naa laipe yii.
Sugbon Anjorin wa nibe bi a ti n soro yii.
O gbe aworan kan jade lojo Eti, nibi ti o ti n ki Jimoo ni Medina.
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…