Is gaju! Awon Iwonyi ni awon oba tuntun ni ilu Ibadan!
Awon agba oye tele, ti won ti wa di oba
1) High Chief Lekan Balogun: Otun Olubadan ti Ibadanland
2) High Chief Eddy Oyewole: Ashipa olubadan ti Ibadanland
3) High Chief Akinloye Owolabi Olakuleyin: Balogun of Ibadanland
4) High Chief Tajudeen Ajibola: Osi Balogun of Ibadaland
5) High Chief Latifu Gbadamosi Adebimpe: Asipa Balogun of Ibadanland
6) High Chief Dr Kolawole Adegbola: Ekarun Blaogun of Ibadanland
7) High Chief Abiodun Kola-Daisi: Ekerin Olubadan of Ibadanland
8) High Chief S. Amidu Ajibade: Ekarun Olubadan of Ibadanland
Nigba ti won so awon bale metala di oba, ade oba n duro de awon baale kan ti won ko tii je ni agbegbe tiwon.
Awon baale to ti di oba ni:
1) Chief Lasisi Akano: Onijaye of Ijaye
2) Chief Ismaila Olasunkanmi: Oniroko of Iroko
3) Chief Moses Olasunkanmi: Onikereku of Ikereku
4) Chief Mudasiru Omodele Adebayo: Baale Olodo
5) Chief Victor Sunday Okunola: Elegbeda of Egbeda
6) Alhaji Wahab Olabamiji Okedina: Baale Okelade-Okin
7) Chief Olabamiji Ahmed Thomas: Alakufo of Akufo
8) Chief Gbolagade Muritala Babalola: Onido of Ido
9) Chief Dauda Omotoso: Baale Awotan
10) Chief Tiamiyu Labiyi Ladipo: Baale of Abanla
11) Chief James Oladipo Obisesan: Baale Akanran naa di His Royal Highness
Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole
Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…