Home iroyin Abiodun olokada fe pokunso tori ko ri N50,000 to ya lowo LAPO san
iroyin - August 26, 2017

Abiodun olokada fe pokunso tori ko ri N50,000 to ya lowo LAPO san

Arakunrin kan to so pe oun ya owo lowo banki ti a mo si LAPO Microfinace Bank, Abiodun Onipede, ti so pe airi owo naa san lo je ki oun fe p’okun so.

Aipe yii ni awon agbofinro Civil Defence ka Abiodun mo ibi to ti fe p’okunso ni agbegbe Abeokuta.

Die lo ku lojo naa, tori o ti so okun m’ogi, ko torun bo o lo ku.

Abiodun ni aisi owo naa lo je ki oun kuro ni ile iwe giga Federal College of Education, Osiele, to si je pe airowo naa lo je ki omo oun kan ku si osibitu.

Sibesibe, awon olopaa ni awon maa gbe Abiodun lo si ile ejo, tori ese ni ki enikenei fe gbemi ara re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…