Home iroyin Ààre ẹgbẹ́ Aatren sèkìlò f’áwọn af’adé d’ógun sílẹ̀.
iroyin - August 26, 2017

Ààre ẹgbẹ́ Aatren sèkìlò f’áwọn af’adé d’ógun sílẹ̀.

Lojobo,Toside ojo ketadinlogun osu kejo
odun yii nipade olojo kan idanileko ohun waye ni papa isere Onikan
nipinle Eko nibi ti egbe elesin isese lapapo nipinle naa,iyen
Association of African Traditional Religion in Nigeria &
Overseas(AATREN)ti parapo se eto adura f’orileede yii lapapo ati
idanilekoo nla fawon omo egbe lati gbogbo ijoba ibile to yi ipinle
gbogbo ka.Ninu oro Aare egbe naa,Oloye Ifasegun Elegusi to tun je
Opemoluwa tile Ikate fi emi imoore re han si itesiwaju to n ba egbe
ohun lekajeka ati esin isese lapapo,o dupe lowo gbogbo lobaloba to
f’aafin won sile wa sibi ayeye ohun;leyin eyi lo se ikilo fawon elesin
isese atawon onisegun ti won n je oye alade kaakiri lati bowo fawon to
de ade ilu.O ran won leti pe asiko ati igba wa fun ade didee tiwon ati
ibiti won ti le de e sugbon tawon oba alade lee de tiwon nigba gbogbo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…